African Spiritual Aid

Tuesday, 16 May 2017

ORIKI IFA [IN PRAISE OF ORUNMILA ''BABA IFA'']

ORIKI ORUNMILA

 Orunmila, ajomisanra, igba keji Olodumare Eleri Ipin,
Omo ope kan ti nsoro dogi dogi, Ara Ado, Ewi, ara Igbajo,ara Iresi, ara Ikole, ara Igeti, ara oke Itase,Ara iwonran ibi ojumo ti nmo waiye akoko Olokun,oro ajo epo ma pon,Olago lagi okunrin ti nmu ara ogidan le, o ba iku ja gba omo e sile,Odudu ti ndu ori emere, o tun ori ti ko sunwon se,Orunmila ajike, Orunmila ajige, Orunmila aji fi oro rere lo. Ase

TRANSLATION:                                                                 The spirit of fate, dew and eternal source of life, word and exultant strength,next to Olodumare, Witness to creation,offspring, palm tree, spark, eternal force.native of Ado EWI, native of Igbajo, Iresi native,native of Ikole, Igeti native, native of Itase Hill,This native generator sea pure mystical is the mostpowerful who gives youthful vitality, who rescueschildren from the wrath of death. The great saviorwho saves youth, he saves the lost, Orunmila is worthy of praise in the morning, Orunmila is worthy of prayers for the good things in life. Ase.

1 comment:

  1. The casino giant opens at 8 a.m. PT | JTM Hub
    With a strong gaming 천안 출장안마 presence and generous player bonuses, 남양주 출장샵 the resort offers a fresh and attractive 군포 출장샵 gaming experience for 전라북도 출장마사지 all. 세종특별자치 출장샵

    ReplyDelete

AROLE OODUA

AROLE OODUA
Ọba Ògúnwùsì Adeyeye Enitan Òjájá (II

EGUNGUN

EGUNGUN
Ancient Astronauts [Spirit of the Ancestors]

ISESE

IFA CONSULTATIONS

IFA CONSULTATIONS
ORACLE OF INFORMATION & COSMOLOGY

IFA WORSHIP

IFA WORSHIP
A World Wide Spirituality

OGUN BIBO

OGUN  BIBO
In Praise of The Active Force of Elements [God of The Blacksmith]

AWEBI'DANU!

OPOLOPO EYAN NI OTI WEE ORISIRISI OSE ATI EBU, TI O KO SI SISE LARARE, NITORI PE ELEDA RE KO BA DA SI GBOGBO OHUN TI OUNSE NI:

IFA IYASI TI ANFI WEE IBI KURO NI ELEDA WA.

eyele funfun, mariwo ope eyo kan, ao ge si 21, ewe esisi 21, ao gun po mo ose iwe ekan, ao fi iyere osun te ifa eji ogbe, ao pe ofore si, ao po mo ose ti a gun, ao le ose yen mo aya eyele funfun ao lo fi wee ori wa si odo toun san, ti a ba we ori tan ao ju eyele yen le si odo ki a to ma bo wa le.

Ofore:
oyun wundia ni ndi ejoo, ipejo ekun aba agba l'eru, asese yo mariwo ope ni wo orun gbarigbari, ase bi eni matu bi eni matu, ase bi eniti ko nitu bi eniti koni tu, awon l'ose ifa fun Orunmila, Ifa nse oun gbogbo nkan, eleda re ko ba dasi, eleda temi 'Lagbaja' omo 'Lagbaja' wa ba mi dasi oro mi, nitori wawa l'omode mbo ko esisi, ifa wa siju Aaje wo mi o, nitori ojurere ni mariwo ope siwo Eledumare, iyere osun lo ni ki won fi gbogbo ire ode ilu sin mi bo, apa tun apa si ni eyele fi nko ire wole, Eji Ogbe ki o gbe gbo ibi kuro l'ori mi.

APEREE

APEREE
Ori Inu [Master of Faith & Destiny]

(ONA=ABAYO) ASINA OWO TO DAJU

=SUGBON MO FE KI ENI TI ONA BATI DIMO TIPE TABI IWO TI OTI LO ORISIRISI ISE ASINA TI KO SISE, KI IRU ENI BE KOKO LO ISE ITUWO AYE YI=

EGBO ATI EWE TUDE DIE, EPO OBO DIE, OKO ATARE KAN, AO GUN PO,
AO FI EYIN ORORO KAN PO'PO DADA; AO TUN GUN EPO OBO DIE PELU OSE, AO WA TU ODIDI IKE LOFINDA MISS PARISI KAN SINU OMI IWE
lilore
AO KOKO FI EYI TI AFI EYIN PO YE PA GBOGBO ARA, LEYIN OGBON ISEJU, AO LO FI EYI TI APO MO OSE YE WE PELU OMI TI ATU LOFINDA SI...

ISE YI DARA PUPO FUN ENI TI ONA BADI MO.

NOW: ASINA OWO

=ORI IKUN, ORI ASIN, ORI OLOGBO, ORI LAGIDO, ORI OWAWA, IYE AGBE, IYE ALUKO, IKODE, EWE ORINJIN, EWE ISAJU, EWE SAWEREPEPE, AFARA OYIN, AO GUN GBOGBO RE MO OSE, AO PA AKUKO ADIYE KAN, AO FI EJERE PO OSE YI PO, AO FI ADIYE YE SE SARA...
LEYIN OJO KETA ODI WIWE NI JO META META

ikilo pataki:
eni ti koba ti pe omo 40 yers ko gbodo se ise yi o, pelu ogo oloun ti iru enibe base koni sise fun: amin KOKI SE PE ISE YI NI ABURU KANKAN TI OLESE FUN ENIYAN SUGBON KODARARA KI OMODE MA SE AWURE OWO, AFI TOBA JE PE O NIDI PATAKI KAN TOFI FESE IRU ISE BE LOKU, MO GBA LADURA PE OGUN KORINA KORILO KO NI JE TIWA O.
AMIN.

FUN IWADI TABI IBERE TABI IWO TI ONI ISORO KAN TI O FE RIWA FUN EPE AGO YI 07039123625/07083379465

TREATMENT

TREATMENT
Eradicate Stretch Marks from Your Skin Fibers...

TRADITIONAL MEDICINE

TRADITIONAL MEDICINE
Alternative Therapy